02/02/2019
Ore ofe la rigba
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from 健康嗎Health Code, Abeokuta.
Agunbiade victory old student Association (AVOSA) Was created by 1996 set on 16th of may 2017 meeting every 3rd Sunday of a month @ Baale olorombo house ijeun titun we implore us to be an active member you can reach us on [email protected]
02/02/2019
Ore ofe la rigba
Maria iya mimo
ire ni gbekele wa
ran wa lowo,da'bo bo wa
Nitori ogo re.
Odun nlo sopin o
baba mimo
fiso re sowa o
tomotomo...........
Eyi ni lati ran gbogbo awa omo ijo mimo leti wipe ki a sora fun oselu eleya meya tabi elesin mesin yio dara fun wa o
Olorun ijo mimo,ranti ileri ti o ba ijo mimo da, sanu fun orileede Nigeria ki o fun wa ni olori titun ti yio tun ilu se. Ti ara yio tu gbogbo eniyan........
06/12/2014
gbagbo, Jesu ni idahun si ohun gbogbo
"Mo n be ninu ododo
Fun dapo awon eni mimo
Ewa ninu idapo
T**i emi o fi pada wa"
Hymn "771"
Eyin omo ijo mimo, eyi ni lati ran ara wa leti wipe aisun osun titun ti o gbehin 2014 yio waye ni Thursday 04/12/2014.e fi sokan
01/12/2014
01/12/2014